Psalms 55:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Alábàárìn mi gbógun ti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀, ó yẹ àdéhùn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti nà ọwọ rẹ̀ si iru awọn ti o wà li alafia pẹlu rẹ̀: o ti dà majẹmu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀rẹ́ mi yìí ti dalẹ̀ èmi ọ̀rẹ́ Rẹ̀; ó ti bá májẹ̀mú Rẹ̀ jẹ́.