Psalms 55:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìhàlẹ̀ ọ̀tá bà mí ninu jẹ́, nítorí ìnilára àwọn eniyan burúkú; wọ́n kó ìyọnu bá mi, wọ́n ń bínú mi, inú wọn sì dùn láti máa bá mi ṣọ̀tá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ohùn ọta nì, nitori inilara enia buburu: nitoriti nwọn mu ibi ba mi, ati ni ibinu, nwọn dẹkun fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sí ohùn àwọn ọ̀ta ni, nítorí igbe àwọn ènìyàn búburú; nítorí wọ́n mú ìjìyà wá sórí mi wọ́n sì kẹ́gàn mi nínú ìbínú wọn.