Psalms 55:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Da èrò wọn rú, OLUWA, kí o sì dà wọ́n lédè rú; nítorí ìwà ipá ati asọ̀ pọ̀ ninu ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, ṣe iparun, ki o si yà wọn li ahọn: nitori ti mo ri ìwa agbara ati ijà ni ilu na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Da àwọn ẹni búburú láàmú, OLÚWA, da ahọ́n wọn rú, nítorí èmi rí ìwà agbára àti ìjà ní ìlú náà.