Psalms 56:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí pé àwọn eniyan ń lépa mi; ọ̀tá gbógun tì mí tọ̀sán-tòru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌLỌRUN, ṣãnu fun mi: nitoriti enia nfẹ gbe mi mì; o mba mi jà lojojumọ, o nni mi lara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, nítorí àwọn ènìyàn ń fi ìgbọ́nára lépa mi; ní gbogbo ọjọ́ ni wọn ń kọjú ìjà sí mi, wọn ń ni mi lára.