Psalms 56:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé o ti gba ẹ̀mí mi lọ́wọ́ ikú, o gbà mí, o kò jẹ́ kí n kọsẹ̀, kí n lè máa rìn níwájú Ọlọrun ninu ìmọ́lẹ̀ ìyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe iwọ li o ti gbà ọkàn mi lọwọ ikú: iwọ ki yio ha gbà ẹsẹ mi lọwọ iṣubu? ki emi ki o le ma rìn niwaju Ọlọrun ni imọlẹ awọn alãye?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ tí gbà mí lọ́wọ́ ikú àti ẹsẹ̀ mi lọ́wọ́ ìṣubú, kí èmí lè máa rìn níwájú Ọlọ́run ní ìmọ́lẹ̀ àwọn alààyè.