Psalms 56:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọ̀tá ń lépa mi tọ̀sán-tòru, ọpọlọpọ ní ń bá mi jà tìgbéraga-tìgbéraga.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọta mi nfẹ igbe mi mì lojojumọ: nitori awọn ti nfi igberaga ba mi ja pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀ta mi ń lé mi ní gbogbo ọjọ́ àwọn ènìyàn ń kọjú ìjà sí mi nínú ìgbéraga wọn.