Psalms 56:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tọ̀sán-tòru ni wọ́n ń da ọ̀rọ̀ mi rú; ibi ni gbogbo èrò tí wọn ń gbà sí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lojojumọ ni nwọn nlọ́ ọ̀rọ mi: ibi ni gbogbo ìro inu wọn si mi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń yí ọ̀rọ̀ mí ní gbogbo ọjọ́ wọn ń gbèrò nígbà gbogbo láti ṣe mí níbi.