Psalms 56:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, san ẹ̀san ẹ̀ṣẹ̀ wọn fún wọn; ninu ibinu rẹ, Ọlọrun, ré àwọn eniyan yìí lulẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ha le ti ipa aiṣedede là? ni ibinu, bi awọn enia na lulẹ̀, Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ha le mú un jẹ gbé? Ní ìbínú Rẹ, Ọlọ́run, wó àwọn ènìyàn yìí lulẹ̀ Ọlọ́run!