Psalms 56:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O sá mọ gbogbo ìdààmú mi; ati bí omijé mi ti pọ̀ tó, wọ́n ṣá wà ní àkọsílẹ̀ ninu ìwé rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ nka ìrìnkiri mi: fi omije mi sinu igo rẹ: nwọn ko ha si ninu iwe rẹ bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kọ ẹkún mi sílẹ̀; kó omije mi sí ìgò Rẹ wọ́n kò ha sí nínú ìkọ̀sílẹ̀ Rẹ bí?