Psalms 57:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣàánú mi, Ọlọrun, ṣàánú mi, nítorí ìwọ ni ààbò mi; abẹ́ òjìji apá rẹ ni n óo fi ṣe ààbò mi, títí gbogbo àjálù wọnyi yóo fi kọjá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ṢÃNU fun mi: Ọlọrun, ṣãnu fun mi: nitoriti ọkàn mi gbẹkẹle ọ: lõtọ, li ojiji iyẹ-apa rẹ li emi o fi ṣe àbo mi, titi wahala wọnyi yio fi rekọja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, ṣàánú fún mi, nítorí nínú Rẹ ni ààbò ọkàn mí wà. Èmi o fi ààbò mí síbi ìyẹ́ apá Rẹ títí tí ewu yóò fi kọjá lọ.