Psalms 57:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dẹ àwọ̀n sí ojú ọ̀nà mi; ìpọ́njú dorí mi kodò. Wọ́n gbẹ́ kòtò sílẹ̀ dè mí, ṣugbọn àwọn fúnra wọn ni wọ́n jìn sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti ta àwọn silẹ fun ẹsẹ mi: nwọn tẹ ori ọkàn mi ba: nwọn ti wà iho silẹ niwaju mi, li ãrin eyina li awọn tikarawọn jìn si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ti ta àwọ̀n sílẹ̀ fún ẹsẹ̀ mi: a tẹ orí ọkàn mi ba nínú ìtìjú wọ́n gbẹ́ kòtò sí ọ̀nà mi: ṣùgbọ́n wọn ti jìn ṣíbẹ̀ fún ara wọn.