Psalms 58:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Olódodo yóo yọ̀ nígbà tí ẹ̀san bá ń ké, yóo fi ẹsẹ̀ wọ́ àgbàrá ẹ̀jẹ̀ àwọn eniyan burúkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olododo yio yọ̀ nigbati o ba ri ẹsan na: yio si wẹ̀ ẹsẹ rẹ̀ ninu ẹ̀jẹ awọn enia buburu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olódodo yóò yọ nígbà a bá ń gbẹ̀san wọn nígbà tí wọn bá wẹ ẹsẹ̀ wọn nínú ẹ̀jẹ̀ ènìyàn búburú.