Psalms 58:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn eniyan yóo wí nígbà náà pé, “Nítòótọ́, èrè ń bẹ fún olódodo; nítòótọ́, Ọlọrun ń bẹ tí ń ṣe ìdájọ́ ayé.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li enia o si wipe, Lõtọ, ère mbẹ fun olododo: lõtọ, on li Ọlọrun ti o nṣe idajọ ni aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn yóò wí pé, “lóòtọ́ èrè àwọn ń bẹ fún olódodo; lóòtọ́ òun ni Ọlọ́run tí ń ṣe ìdájọ́ ní ayé.”