Psalms 58:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti inú oyún ni àwọn eniyan burúkú ti ṣìnà, láti ọjọ́ tí a ti bí wọn ni wọ́n tí ń ṣìṣe, tí wọn ń purọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati inu iya wọn wá li awọn enia buburu ti ṣe iyapa: nwọn ti ṣina lojukanna ti a ti bi wọn, nwọn a ma ṣeke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní inú ìyá wọn wá, ni eniyàn búburú tí sìnà lojukan náà tí a ti bí wọn wọn a máa ṣèké.