bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 58:6
Psalms 58:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kán eyín mọ́ wọn lẹ́nu, Ọlọrun; OLUWA! Yọ ọ̀gàn àwọn ẹgbọ̀rọ̀ kinniun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ká wọn li ehin, Ọlọrun, li ẹnu wọn: ká ọ̀gan awọn ọmọ kiniun nì, Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ká eyín ẹnu wọn, Ọlọ́run; ní ẹnu wọn ká ọ̀gan àwọn ọmọ kìnnìún, OLÚWA.