Psalms 59:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Má pa wọ́n, kí àwọn eniyan mi má baà gbàgbé; fi ọwọ́ agbára rẹ mì wọ́n, ré wọn lulẹ̀, OLUWA, ààbò wa!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe pa wọn, ki awọn enia mi ki o má ba gbagbe: tú wọn ká nipa agbara rẹ; ki o si sọ̀ wọn kalẹ, Oluwa asà wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n má ṣe pa wọ́n, OLÚWA asà wa, kí àwọn ènìyàn mí má ba à gbàgbé. Nínú agbára Rẹ̀, jẹ́ kí wọ́n máa rìn kiri, kí ó sì Rẹ̀ wọ́n sílẹ̀.