Psalms 59:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n fi ẹnu wọn dá, àní, nítorí ọ̀rọ̀ tí wọ́n fi ẹnu wọn sọ, jẹ́ kí ìgbéraga wọn kó bá wọn. Nítorí èpè tí wọ́n ṣẹ́ ati irọ́ tí wọ́n pa,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ẹ̀ṣẹ ẹnu wọn ni ọ̀rọ ète wọn, ki a mu wọn ninu igberaga wọn: ati nitori ẽbu ati èke ti nwọn nṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ẹnu wọn, ni ọ̀rọ̀ ètè wọn, kí a mú wọn nínú ìgbéraga wọn. Nítorí ẹ̀gàn àti èké tí wọn ń sọ,