Psalms 59:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
fi ibinu pa wọ́n run. Pa wọ́n run kí wọn má sí mọ́, kí àwọn eniyan lè mọ̀ pé Ọlọrun jọba lórí Jakọbu, ati títí dé òpin ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Run wọn ni ibinu, run wọn, ki nwọn ki o má ṣe si mọ́: ki o si jẹ ki nwọn ki o mọ̀ pe, Ọlọrun li olori ni Jakobu titi o fi de opin aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pa wọn run nínú ìbínú, run wọ́n di ìgbà tí wọ́n kò ní sí mọ́. Nígbà náà ní yóò di mímọ̀ dé òpin ayé pé Ọlọ́run jọba lórí Jákọ́bù. Sela