Psalms 59:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní alaalẹ́ wọn á pada wá wọn á máa hu bí ajá, wọn á sì máa kiri ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati li aṣalẹ jẹ ki nwọn ki o pada; ki nwọn ki o pariwo bi ajá, ki nwọn ki o si ma yi ilu na ka kiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n padà ní àsálẹ́, wọn ń gbó bí àwọn ajá wọ́n ń rìn ìlú náà káàkiri.