Psalms 59:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn á máa fẹsẹ̀ wọ́lẹ̀, wọn á máa wá oúnjẹ kiri, bí wọn ò bá sì yó wọn á máa kùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki nwọn ki o ma rìn soke rìn sodò fun ohun jijẹ, bi nwọn kò ba yó, nwọn o duro ni gbogbo oru na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ń rín kiri fún oúnjẹ wọn sì ń yán nígbà tí wọn kò yó.