Psalms 59:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wò ó bí wọ́n ṣe lúgọ dè mí! OLUWA, àwọn jàǹdùkú eniyan kó ara wọn jọ láti pa mí lára, láìṣẹ̀, láìrò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sa kiyesi i, nwọn ba ni buba fun ọkàn mi, awọn alagbara pejọ si mi; kì iṣe nitori irekọja mi, tabi nitori ẹ̀ṣẹ mi, Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wòó, bí wọ́n ṣe ba ní bùba dè mí! Àwọn alágbára ń gbìmọ̀ lòdì sí mi Kìí se nítorí ìrékọja mi tàbí ẹ̀ṣẹ̀ mí, OLÚWA.