Psalms 59:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní alaalẹ́, wọn á pada wá, wọn á máa hu bí ajá, wọn a sì máa kiri ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn pada li aṣalẹ: nwọn npariwo bi ajá, nwọn nrìn yi ilu na ka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n padà ní àṣálẹ́, wọ́n ń gbó bí àwọn ajá, wọ́n ń rìn yí ìlú náà káàkiri.