Psalms 59:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ ohun tí wọn ń sọ jáde lẹ́nu, ẹ wo ahọ́n wọn bí idà; wọ́n sì ń wí ninu ara wọn pé, “Ta ni yóo gbọ́ ohun tí à ń sọ?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, nwọn nfi ẹnu wọn gùfẹ jade: idà wà li ète wọn: nitoriti nwọn nwipe, tali o gbọ́?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí ohun tí wọ́n tú jáde ní ẹnu: wọn ń tú idà jáde láti ètè wọn, wọn sì wí pé, “Ta ní ó le gbọ́ ọ̀rọ̀ wa?”