Psalms 59:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ìwọ OLUWA ń fi wọ́n rẹ́rìn-ín, o sì ń fi gbogbo orílẹ̀-èdè ṣe yẹ̀yẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn iwọ, Oluwa, yio rẹrin wọn: iwọ ni yio yọṣuti si gbogbo awọn keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ìwọ, OLÚWA, yóò fi wọ́n rẹ́rin-ín Ìwọ ó yọ ṣùtì sí gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè.