Psalms 6:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ojú yóo ti gbogbo àwọn ọ̀tá mi; ìdààmú ńlá yóo bá wọn, wọn óo sá pada, ojú yóo sì tì wọ́n lójijì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju yio tì gbogbo awọn ọta mi, ara yio sì kan wọn gogo: nwọn o pada, oju yio tì wọn lojíji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọ̀tá mi lójú yóò tì, wọn yóò sì dààmú; wọn yóò sì yípadà nínú ìtìjú àìròtẹ́lẹ̀.