Psalms 6:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí kò sí ẹni tí yóo ranti rẹ lẹ́yìn tí ó bá ti kú. Àbí, ta ló lè yìn ọ́ ninu isà òkú?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti kò si iranti rẹ ninu okú: ninu isa okú tani yio dupẹ fun ọ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnikẹ́ni kò sì rántí Rẹ nígbà tí ó bá kú. Ta ni yóò yìn ọ́ láti inú iṣà òkú?