Psalms 6:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìbànújẹ́ sọ ojú mi di bàìbàì, agbára káká ni mo fi lè ríran nítorí ìnilára àwọn ọ̀tá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi bajẹ tan nitori ibinujẹ; o di ogbó tan nitori gbogbo awọn ọta mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú mi di aláìlera pẹ̀lú ìbànújẹ́; wọ́n kùnà nítorí gbogbo ọ̀tá mi.