Psalms 60:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ràn wá lọ́wọ́, bá wa gbógun ti àwọn ọ̀tá wa, nítorí pé asán ni ìrànlọ́wọ́ eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori pe asan ni iranlọwọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ lórí àwọn ọ̀tá, nítorí asán ní ìrànlọ́wọ́ ènìyàn.