Psalms 60:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti ta àsíá ogun fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ, kí wọ́n baà lè rí ààbò lọ́wọ́ ọfà ọ̀tá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti fi ọpagun fun awọn ti o bẹ̀ru rẹ, ki a le ma fi i hàn nitori otitọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀ ní ìwọ fi ọ̀págun fún kí a lè fíhàn nítorí òtítọ́. Sela