Psalms 60:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun ti sọ̀rọ̀ ninu ilé mímọ́ rẹ̀, ó ní, “Tayọ̀tayọ̀ ni n óo fi pín Ṣekemu, n óo sì pín àfonífojì Sukotu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun ti sọ̀rọ ninu ìwa-mimọ́ rẹ̀ pe; Emi o yọ̀, emi o pin Ṣekemu, emi o si wọ̀n afonifoji Sukkotu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ láti ibi mímọ́ Rẹ̀: “Ní ayọ̀, èmi ó pín ṣèkémù jáde èmi o sì wọ̀n àfonífojì ṣúkótù.