Psalms 61:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí ìwọ ni ààbò mi, ìwọ ni ilé ìṣọ́ tí ó lágbára láti dáàbò bò mí lọ́wọ́ ọ̀tá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ li o ti nṣe àbo fun mi, ati ile-iṣọ agbara lọwọ ọta nì.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ ti jẹ́ ibi ààbò mi, ilé ìsọ́ agbára àwọn ọ̀tá.