Psalms 62:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n fẹ́ ré e bọ́ láti ipò ọlá rẹ̀. Inú wọn a máa dùn sí irọ́. Wọ́n ń fi ẹnu wọn súre, ṣugbọn ní ọkàn wọn, èpè ni wọ́n ń ṣẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiki ìro wọn ni lati já a tilẹ kuro ninu ọlá rẹ̀: nwọn nṣe inu didùn ninu eke: nwọn nfi ẹnu wọn sure, ṣugbọn nwọn ngegun ni inu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kìkì èró wọn ni láti bì ṣubú kúrò nínú ọlá Rẹ̀; inú wọn dùn sí irọ́. Wọn ń fi ẹnu wọn súre, ṣùgbọ́n wọ́n ń gégùn nínú ọkàn wọn. Sela