Psalms 62:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun nìkan ni mo fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé, nítorí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi ti wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkàn mi, iwọ sa duro jẹ de Ọlọrun; nitori lati ọdọ rẹ̀ wá ni ireti mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú Ọlọ́run nìkan ni ìsinmí wà, ìwọ Ọlọ́run mi. Ìrètí mi wá láti ọ̀dọ̀ Rẹ.