Psalms 63:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn tí ń wá ọ̀nà láti gba ẹ̀mí mi yóo sọ̀kalẹ̀ lọ sinu isà òkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ti nwá ọkàn mi lati pa a run, nwọn o lọ si iha isalẹ-ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó ń wá ọkàn mí ní a ó parun; wọn o sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìṣàlẹ̀ ilẹ̀ ayé.