Psalms 64:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí àwọn olódodo máa yọ̀ ninu OLUWA, kí wọ́n sì máa wá ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀! Kí gbogbo ẹni pípé máa ṣògo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olododo yio ma yọ̀ nipa ti Oluwa, yio si ma gbẹkẹle e; ati gbogbo ẹni-iduro-ṣinṣin li aiya ni yio ma ṣogo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí Olódodo kí o yọ̀ nínú OLÚWA yóò sì rí ààbò nínú Rẹ̀ Gbogbo ẹni ìdúró ṣinṣin ni àyà yóò máa yìn ín.