Psalms 64:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n ń sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí aláìṣẹ̀ láti ibùba wọn, láìbẹ̀rù, wọ́n ń ta ọfà ọ̀rọ̀ sí i lójijì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o le ma tafà ni ìkọkọ si awọn ti o pé: lojiji ni nwọn tafa si i, nwọn kò si bẹ̀ru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n tafà ní kọ̀kọ̀ sí àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀: wọ́n tafà sí lojijì, wọn kò sì bẹ̀rù.