Psalms 64:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo pa wọ́n run nítorí ohun tí wọ́n fi ẹnu wọn sọ; gbogbo ẹni tí ó bá rí wọn ni yóo máa mirí nítorí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni ahọn wọn yio mu wọn ṣubu lu ara wọn: gbogbo ẹniti o ri wọn yio mì ori wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ahọ́n wọn yóò sì dojú ìjà kọ wọ́n, yóò sì run wọ́n Gbogbo ẹni tí ó bá rí wọn yóò sì mi orí fún wọn.