Psalms 65:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ẹran ọ̀sìn bo pápá oko bí aṣọ, ọkà bo gbogbo àfonífojì, ó sì so jìngbìnnì, wọ́n ń hó, wọ́n sì ń kọrin ayọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Agbo ẹran li a fi wọ̀ pápá-tútù na li aṣọ: afonifoji li a fi ọka bò mọlẹ: nwọn nhó fun ayọ̀, nwọn nkọrin pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà, ni asọ; àfonífojì ni a fi ọkà bò mọ́lẹ̀, wọn hó fún ayọ̀, wọn ń kọrin pẹ̀lú.