Psalms 65:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o yàn, tí o mú wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, láti máa gbé inú àgbàlá rẹ. Àwọn ire inú ilé rẹ yóo tẹ́ wa lọ́rùn, àní, àwọn ire inú tẹmpili mímọ́ rẹ!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alabukún-fun li ẹniti iwọ yàn, ti iwọ si mu lati ma sunmọ ọdọ rẹ, ki o le ma gbe inu agbala rẹ wọnni: ore inu ile rẹ yio tẹ́ wa lọrùn, ani ti tempili mimọ́ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ni fún àwọn tí o yàn tí o mú wa láti máa gbé àgọ́ Rẹ! A tẹ wá lọ́rùn pẹ̀lú ohun rere inú ilé Rẹ, ti tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ.