Psalms 65:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iṣẹ́ òdodo tí ó bani lẹ́rù ni o fi dá wa lóhùn, Ọlọrun olùgbàlà wa. Ìwọ ni gbogbo àwọn tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé gbẹ́kẹ̀lé, ati àwọn tí wọn wà lórí omi òkun ní ọ̀nà jíjìn réré.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun iyanu nipa ododo ni iwọ fi da wa lohùn, Ọlọrun igbala wa: ẹniti iṣe igbẹkẹle gbogbo opin aiye, ati awọn ti o jina réré si okun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ dá wa lóhùn pẹ̀lú ohùn ìyanu ti òdodo, Ọlọ́run olùgbàlà wa, ìrètí gbogbo òpin ayé àti àwọn tí ó jìnnà nínú òkun,