Psalms 65:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí ń gbé ìpẹ̀kun ayé sì ń bẹ̀rù nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ; o mú kí àwọn eniyan, láti ìlà oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀, hó ìhó ayọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn pẹlu ti ngbe apa ipẹkun mbẹ̀ru nitori àmi rẹ wọnni: iwọ mu ijade owurọ ati ti aṣalẹ yọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó ń gbé òkèrè bẹ̀rù agbára Rẹ̀: ìwọ mú ìjáde òwúrọ̀ àti ti àṣálẹ̀ yọ ìwọ pé orin ayọ̀ jáde.