Psalms 65:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ò ń ṣìkẹ́ ayé, o sì ń bomi rin ín, o mú kí ilẹ̀ jí kí ó sì lẹ́tù lójú; o mú kí omi kún inú odò ìwọ Ọlọrun, o mú kí ọkà hù lórí ilẹ̀; nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni o ṣe ṣètò rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ bẹ aiye wò, o si bomi rin i: iwọ mu u li ọrọ̀, odò Ọlọrun kún fun omi: iwọ pèse ọkàn wọn, nigbati iwọ ti pèse ilẹ bẹ̃.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ bẹ ayé wò, o sì bomirin; ìwọ mú ní ọ̀rọ̀ púpọ̀. Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run kún fún omi láti pèsè ọkàn fún àwọn ènìyàn, nítorí ibẹ̀ ní ìwọ ti yàn án.