Psalms 66:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nípa agbára rẹ̀ ó ń jọba títí lae. Ó ń ṣọ́ àwọn orílẹ̀-èdè lójú mejeeji, kí àwọn ọlọ̀tẹ̀ má gbéraga sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O jọba nipa agbara rẹ̀ lailai; oju rẹ̀ nwò awọn orilẹ-ède: ki awọn ọlọtẹ ki o máṣe gbé ara wọn ga.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O ń jọba títí láé nípa agbára Rẹ̀, ojú Rẹ̀ ń wò orílẹ̀ èdè kí àwọn ọlọ̀tẹ̀ má ṣe gbé ara wọn ga. Sela