Psalms 67:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kí gbogbo ayé lè mọ ọ̀nà rẹ̀; kí gbogbo orílẹ̀-èdè sì mọ ìgbàlà rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ọ̀na rẹ ki o le di mimọ̀ li aiye, ati igbala ilera rẹ ni gbogbo orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
kí ọ̀nà Rẹ̀ le di mímọ̀ ní ayé, ìgbàlà Rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè.