Psalms 67:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí inú àwọn orílẹ̀-èdè ó dùn, kí wọn ó máa kọrin ayọ̀, nítorí pé ò ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan láìṣe ojuṣaaju; o sì ń tọ́ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki inu awọn orilẹ-ède ki o dùn, ki nwọn ki o ma kọrin fun ayọ̀: nitoriti iwọ o fi ododo ṣe idajọ enia, iwọ o si jọba awọn orilẹ-ède li aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí orílẹ̀ èdè kí o yọ̀, kí o sì kọrin fún ayọ̀, nítorí ìwọ fi òdodo darí àwọn ènìyàn ìwọ si jọba àwọn orílẹ̀-èdè ní ayé.