Psalms 68:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ọba ni ó sá tàwọn tọmọ ogun wọn; àwọn obinrin tí ó wà nílé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọba awọn ẹgbẹ ogun sa, nwọn sa lọ: obinrin ti o si joko ni ile ni npin ikogun na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àwọn ọba àti àwọn ológun yára sálọ; Obìnrín tí ó sì jókòó ni ilé ní ń pín ìkógun náà.