Psalms 68:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ati àwọn tí ó wà ní ibùjẹ ẹran rí ìkógun pín: fadaka ni wọ́n yọ́ bo apá ère àdàbà; wúrà dídán sì ni wọ́n yọ́ bo ìyẹ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ẹnyin dubulẹ larin agbo ẹran, nigbana ni ẹnyin o dabi iyẹ adaba ti a bò ni fadaka, ati ìyẹ́ rẹ̀ pẹlu wura pupa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ẹ̀yin sùn láàrin àwọn àgọ́ iná, nígbà náà ni ẹ̀yin ó dàbí apá àdàbà ti a bò ní sílífa.”