bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 68:14
Psalms 68:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Olodumare tú àwọn ọba ká, ní òkè Salimoni, yìnyín bọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Olodumare tú awọn ọba ká ninu rẹ̀, o dabi òjo-didì ni Salmoni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà ti Olódùmarè fọ́n àwọn ọba ká ní ilẹ̀ náà, ó dàbí òjò dídi ní Salímónì.