Psalms 68:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dájúdájú, OLUWA yóo fọ́ orí àwọn ọ̀tá rẹ̀; yóo fọ́ àtàrí àwọn tí ń dẹ́ṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Ọlọrun yio fọ ori awọn ọta rẹ̀, ati agbari onirun ti iru ẹniti nrìn sibẹ ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò tẹ orí àwọn ọ̀tá Rẹ̀, àti agbárí onirun àwọn tó ń tẹ̀ṣíwájú nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn