Psalms 68:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
A ti rí ọ, Ọlọrun, bí o tí ń yan lọ, pẹlu ọ̀wọ́ èrò tí ń tẹ̀lé ọ lẹ́yìn. Ẹ wo Ọlọrun mi, ọba mi, bí ó ti ń yan wọ ibi mímọ́ rẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti ri ìrin rẹ, Ọlọrun; ani ìrin Ọlọrun mi, Ọba mi, ninu ibi mimọ́ nì.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ti rì ìrìn Rẹ, Ọlọ́run, irin Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ Rẹ̀.